Translator
AjeCoin

Loading

Yoruba Version

OWO OFE AJE – AJE COIN

 

Ìtumọ̀ ajé lerefee túmọ sí agbára ọrọ̀ ati ọrọ ajé, ìlọsíwájú olokun ní ìlànà ìṣe ẹyà yoruba ni orilẹ ede Nàìjíríà, áfíríkà àti awon eya Gúúsù Amerika ni a n pe mo oro igbega, eto ìṣúná to duro giri lati ọjọ Ajé tí o jẹ ọjọ àkọkọ leyin ojo isinmi lati bẹrẹ ọ̀sẹ̀ títún ti wọn sì ni igbagbo pé o jẹ ọjọ kan  ti a fi ṣe ìpìlẹ ere jijẹ́ lọpọ yanturu ninu oko owo won leyin ti wón bá ti ṣiṣẹ ti wọn sì tí sinmi ni ojo aiku.

Wọn ni ìgbàgbọ pé Ajé jẹ ayanfe ọmọbìnrin kan soso ti Orisa Olokun bi, eyi túmọ sí pé Olokun ní ọ bí ajé Si Orile ayé, òun sì ni ààyò ti olokun ma nràn ni iṣẹ akanṣe ti o máa n lo agbara iyipada sì ọlọrọ ti yoo mu igbega ba ọrọ ajé laarin ileto rẹ ati awọn ilu tí o sunmọ agbegbe rè ti àwon ènìyàn ti o mọ ọn, ẹ̀mí rẹ sí ni bẹ sibe pelu iṣẹ agbara rẹ sí àwon Yorùbá àti awọn eya miiran ti o ni ìgbàgbọ nínú ìtàn rẹ titi di oni. Ìkíni láàrin awon oloja ni pe AJE A WỌ́GBA / AJE A WA eyi túmọ sí pé àwọn yóò ta atajere ti imisi ajé ba dapo mọ ọjà wọn pẹlu agbara Olodumare ti o fi idi rẹ̀ múlẹ láàrin awon yoruba ati awọn eya Gúúsù Amẹ́ríkà.

Àmì ohun ọ̀ṣọ́  (funfun okun ati ọwọ ẹyọ) ti a tun mọ sí Ajé tabi Ajé olokun eyi ti a le ri ni agbègbè òkun tàbí inu okun.

Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé lórí Eko, Asa, itan ìpìlẹ Ajecoin,ile,ilu Yoruba, Ajé Olokun ati afririka lapaapo, ẹ le kan sí ẹrọ Alatagba was lori ikanni yutuubu Ajecoin.   https://www.youtube.com/@ajecoincommunity?sub_confirmation=1

 

Owo Ajé (Aje Coins) ni owo nina lori afefe (kiripito) , Iwoye ogbon Afrika ati awọn eniyan Se agbekale láti bẹrẹ, jẹ igbadun ati mú u duro ṣinṣin pẹlú àwùjọ eniyan afrika ati awọn oludokowo káàkiri àgbáyé ki wọn lè gbegi dina ipenija to n dojuko eto ìṣúná awọn eya Yoruba ati lati mú ayipada ati ida ààbò bo àwùjọ awọn yoruba ati èèyàn áfíríkà nipa àsà àti iṣe wọn nínu ayé díjítà ati ọja agbaye pẹlu afojusun fún iwulo eya Yoruba , àwùjọ áfíríkà, Guusu Amerika ati awọn eya ti wọn n ba se idokowopọ lágbayé.

Owo-Ajé (Aje Coins) ni yóò se Iro ni lágbára ati mímú ìgbésí ayé gbilẹ, ètò orò aje, iṣẹ ọnà, eto ẹkọ, ilera,, esin/ ìrìn àjò iṣẹ ẹ̀mí, idanilaraya, iṣejoọba, imo ijinlẹ, àwon onísòwò àti nípa ṣiṣe iṣokunfa ìfọwọ́sowọ́pọ̀ , ààbò  idunadura olowo pọ́ọ́kú ti o kun fun ọrọ̀ àṣà ọjà tita ti a mẹnuba ṣaaju.

Atẹjade ìwé yìí yóò ṣe afihan, iṣiniloju , ẹrọ imọ ijinlẹ, ifowo- dokowo ati itonisona nípa koinsi ajé ti o ṣẹ̀ṣẹ̀ n gbaradi láti gbinaya ati fún ikowojọ awọn mùtúmùwà.

Gẹgẹ bi alawọ dudu a le sise yi kì o tayọ nitori a ni ọgbọn ati awujo ti o tobi julo Lagbaye nítorí òwò ori afefe (kiripito)  nípa atọka aworan iṣiro ati isipopada. É jé kí a jumọ bẹrẹ iṣẹ yí ni wàrà- ǹ-ṣesà.

Afojusun ati Ìpinnu

Afojusun : láti pèsè ètò ọrọ ajé díjítà/ Onimo ẹrọ ayara bi asṣa ti yóò dúró ṣiṣin , ti yóò sí mú ayipada  ati igbega’ itẹsiwaju fún awọn eya Yorùbá àti àwùjọ Áfíríkà bati bi a ṣe nṣe ìpèsè ona abayọ sinoja kereje-kereje.

Ìpinnu

Lati se igbega, ìdáàbòbò ati ìdúró ṣinṣin ẹyà Yoruba, iwo oòrùn Áfíríkà, àwùjọ áfíríkà, Guusu Amẹrika, ẹ̀yà dúdú l’amerika ati awọn ti o fi ara pẹ ìwà, iṣe ati aṣa ẹ̀kọ́ abinibi Áfíríkà pẹlu ajọṣepọ ìmọ ẹrọ ìgbàlódé nipasẹ, imo ijinlẹ ẹ̀rọ ti o n so gbogbo owo, idunadura o ti a le fisan owó láàrin awọn ti wọn jùmọ̀ ṣe owo pọ̀ ki wọn lè lu aluyọ nínú ọrọ ajé wọn lágbayé.

Afojusun ati Ìpinnu

Afojusun : láti pèsè ètò ọrọ ajé díjítà/ Onimo ẹrọ ayara bi asṣa ti yóò dúró ṣiṣin , ti yóò sí mú ayipada  ati igbega’ itẹsiwaju fún awọn eya Yorùbá àti àwùjọ Áfíríkà bati bi a ṣe nṣe ìpèsè ona abayọ sinoja kereje-kereje.

Ìpinnu

Lati se igbega, ìdáàbòbò ati ìdúró ṣinṣin ẹyà Yoruba, iwe oòrùn Áfíríkà, àwùjọ áfíríkà, Guusu Amẹrika, ẹ̀yà dúdú l’amerika ati awọn ti o fi ara pẹ ìwà, iṣe ati aṣa ẹ̀kọ́ abinibi Áfíríkà pẹlu ajọṣepọ ìmọ ẹrọ ìgbàlódé nipasẹ, imo ijinlẹ ẹ̀rọ ti o n so gbogbo owo, idunadura o ti a le fi san owó láàrin awọn ti wọn jùmọ̀ ṣe owo pọ̀ ki wọn lè lu aluyọ nínú ọrọ ajé wọn lágbayé

2.

 

Ìdí pataki ati iwulo

A ṣe agbekalẹ kan-in-si ajé fún:

Fún ṣíṣe paaṣi-paarọ̀ ati láti pèsè fún awọn Yorùbá, omo Naijiria lapapọ ati àwùjọ tó sàn mọ láàrin awon Afirika gẹgẹ bi owo to ni wọlé loṣooṣu lati ibẹrẹ dé òpin iṣẹ akanṣe airdrop ti ko l’opin

Lati se iranwo fún ebi ati lati ṣe anna eto iranwọ fún idena iṣe oun oṣi ti o n ba awọn Yorùbá, ọmọ Naijiria, owo olosoosu Ajo Pan Áfríkà fún àjọ UBI, gbigbọ akopa fún ẹtọ yii yi o bere lati ibẹrẹ dé òpin.

Wọn yóò se iranwo owo sisan ní ìlànà ẹrọ díjítà labẹle ati l’ọja ìgbàlódé fún awọn nnkan bi ogunọna ti a fi ọwọ́ ṣe lọ́ṣọ̀ọ́, ohun ọ̀ṣọ́ lorisirisi, ounjẹ, àti iṣe pẹlu ọna isanwo lorisirisi a.b.b.l.

Ṣiṣe eto owo sisan ní ìlànà díjítà, eto ìlera, pẹlu ajọṣepọ awọn ẹlẹri ilera ìgbàlódé ti yóò mú ọna isanwo eto ìlera rọrun nípa lílo ẹrọ dígítà, onírúurú owo alailera ati ọwọ eko iṣewadi ilera ati eti atinuda ohun elo títún nípa ewe ati egbo, eroja asaraloore ati gbigba ẹrọ ìgbàlódé wole lọnà ti yóò mú ẹrọ ìlera gbooro nile afrika lati ṣẹgun awọn iṣoro ti o n dojukọ ẹrí ìlera ati láti pèsè iṣẹ lọpọ yanturu ni Gbogbo ilẹ áfíríkà pàápàá jùlọ ni ẹka eto ìlera.

Ìmọ sáyẹnsì ati ìmọ ẹrọ: iṣẹ iwadii ati eti atinuda.

Ṣiṣẹda ẹrọ ẹrọ gbogbongbo ti yóò mú ọrọ ajé rú gọ́gọ́ síi lati fi ààyè òróró ajé gba awọn ẹnu ibodè áfíríkà àti gúúsù amẹrika ni jakejado àgbáyé pàápàá jùlọ nípa káràkátà káàkiri  ọja áfíríkà, ohun elo àti iṣe ni owo ti ko gara ati aabo lori owo idiye lẹ ọja.

 

3.

Blockchain technology

Kan-in-si ajé ni sis pẹlu open network(TON), ti owo ìṣípàrọ̀ rẹ kò wọn ti o si n ṣiṣe bi ẹrọ ayara bi asa . TON je ẹrọ ti o n da ṣiṣe laini atokun ni kiakia, tibi sí ṣe é fi ọkàn tan Lai fi igba kan bọ ọkan nínú ìbádòwòpọ̀ wọn

4.

Iṣuna ọrọ ajé

Apapọ ti a pèsè: Biliọnu ọta -le-loodunrun le mílíọ̀nù meje (367) kan-in-si aje

Ipin

5.

Airdrop: ida ogun nínú ọgọrùn (20%) Biliọnu meta le laadorin le milionu merin

Crowdfunding: ida ọgbọn nínú ọgọrùn(30%)  biliọnu m’ọkan le laadorin le ni millionu marundin logorun (95.75 billion token)

Ipolowo ati ajọṣepọ owo: ida meedogun nínú ọgọrùn 15% biliọnu marundinlogorun ati milionu márùn un(55.05 billion token)

 

Àpamọ: ìdá mẹwàá nínú ọgọrùn (10%) Biliọnu meta din l’ogijo le millionu meje (36.7 billion token)

Oye owo ti o wa fún idokowo : a o máa fí tó wà leti lojo iwaju

 

5.

Airdrop strategy:

Ipolongo Kain-in-si ajé yóò Pin ida ogun nínú ida ọgọrun nínú gbogbo ida ti a kọ sita fún awọn ti o tẹwọ gbà àní ibẹrẹ pẹ̀pẹ̀ . Awọn ti yóò kó ipa ni:

Awọn alatilẹyin  ifowodokowo pọ

Awọn akopa ti o farajin nínú ikopa lójoojúmó ( b.a. awọn ti wọn fi awọn eniyan ṣọwọ́ sí wa, awon ti wọn ṣiṣe ikede lori ẹrọ ayelujara a.b.b.l.)

A o se idaniloju/ itopinpin apo ikowo wọn lati owo KYC

6.

Ipolongo ifowodokowo po ọ̀gọ̀rọ̀ eniyan:

Kan-in-si ajé yóò ṣe ikowojo fún billion Kan àbọ owo dọ́lá ( $1.5 billion) lati ará ifowodokowo po ọ̀gọ̀rọ̀ eniyan.

A o pin owo yi lẹẹ sí:

Blockchain development: is ogun nínú ọgọrùn (20%)

(Cooporate community building programmes project )ida ogoji nínú ida ọgọrun awọn iṣẹ akanṣe bíi ilé kíkọ ni awọn ile iṣẹ nla nlá, lati le kógo jari nínú

awọn àlàálẹ̀ 21 Pan Áfríkà jakejado àgbáyé RACEE: 40%

Owo ìná lọ lẹ́nu iṣẹ: 15% ida meedogun nínú ida ọgọrun

Owo ìbámu ofin: 10% ida mẹwàá nínú ida ọgọrun

Awọn ti o gbowo sile yóò gba èrè àfikún pẹlu ibamu iye ti wọn dá.

 

Utility and Governance

IKan-in-si ajé ni ṣiṣe ní ònà meji yii:

Fífi san owó fún  : ounjẹ, iṣẹ, ìlera, ifunni lowo ati iha. Àmì ẹyẹ, ẹkọ kíkọ ati awọn nnkan mìíràn láàrin awon eya Yorùbá, Naijiria, Pan Áfríkà, díjítà Lagbaye, ati ọja abẹ́lé

Ìṣèjọba (governance )

Awọn igbimọ to kan-in-si ajé to yanrantí/ awọn akopa ke dibo lati se awọn iṣẹ akanṣe ti wọn ni silẹ nipasẹ ọna idari awọn (CBG)

 

8.

Ìdáàbòbò ati Ibamu

Kan-in-si ajé fi ara mọ òfin to dé àlàálẹ̀ owo Lagbaye pẹlu Pan áfíríkà, gúúsù amẹrika ati òfin ìṣúná owo kaakiri àgbáyé. Abo to pe ye lori awọn ti wọn n fi owo ori afefe ṣòwò ati ifipamo awọn akọsilẹ wọn lori ẹrọ alatagba .

9.

Aworan atẹ Ìtọ́nisọ́nà (Roadmap)

 

Ipele akọkọ: gigbe atẹjade ìwé jade,

kiko airdrop jade bi ọmọ títún, ìpolongo fún ifowodokowo ọlọ́gọ̀ọ̀rọ̀ eniyan (Q1 & Q2 2025)

 

Ipele keji

Ṣaaju ibẹrẹ ọja ati kikọ iye owo/ iye ti a o ta sita Q3 2025

 

Ipele kẹta

Gbigbe àpamọ kan-in-si ajé ati iṣafilọ́lẹ̀ àpò (app) ti wọn yóò ma fi san owó lori foonu oun ẹrọ ayelujara Q3/4 2025

 

Ipele

kẹrin

Ṣiṣe ajọṣepọ pẹlu awọn eya Yorùbá, Pan Áfríkà ati gbogbo oja  lagbaye Q4 2025

 

Ipele  karun ùn

Gbígbòòrò dé guusu Amerika ati jakejado oja lagbaye  Q2 2026

 

Ipele kefa

Itẹsiwaju nínú gbígbalẹ̀ síi ati idagbasoke síi

10.

Ìkọ ati Oludamọran

Kan-in-si aje jẹ imisi iran ati atinuda ti a fún awọn ti o ni òye ti o tayọ ti wọn ni ṣi ọgbọn  ti o rinlẹ̀ ti o si tayọ oyè eda pẹlu awọn igbimọ to duro deede ti wọn sì ni imò ijinlẹ nípa data lati se akọsilẹ pẹlu awọn akosrmose nípa iṣiro owo ti o n woke ti o n jade

11.

Ipolowo ati idagbasoke agbegbe

Ipolowo kan-in-si ajé mú ẹ̀rọ ayélujára lókun kudun, pẹlu awọn Pan African ati awọn orílè èdè lagbaye.

Idanilekoo ati àpérò ẹ̀kọ́, ìtẹ̀wéjade ati ipolongo, ìfitónilétí nípa pàtàkì ati gbigba kan-in-si afẹfẹ ni asiko ayé díjítà ati lati mú abo to péye wá fún awọn to ti bà wa f’owo po ki ontaja ati ontaja le ti pade fún ki o ké fi aaye gba ojúkòró tí kìí pa ojúkòró jẹ èyí yíò jẹ kinikan awọn onibara balẹ lori ohun ti wọn ra ati ọwọ ti wọn san ati aabo to daju lori àkọsílẹ wọn lọdọ oludokowo wọn pàápàá jùlo awọn pẹlu igbimo Pan Áfríkà lori awọn iṣẹ ọnà, awọn ọjà títà, eto ẹkọ ati awọn nnkan mìíràn.

Nini àjọ̀ṣepọ̀ pẹlu awọn gbajumo lori ẹrọ ayélujára, awọn ọba/ aṣojú, awon olokoowo nla. Kekere ati ti oke okun, wọn yóò mú ayipada ba oja wa pẹlu ibamu àlàálẹ̀/ afojusun  Pan Afrika, gbogbo eyi wa lori ẹrọ alatagba Pan ajecoin.io

Lilo ipolowo lori ẹrọ ayelujara ati ipolongo ojukoju káàkiri lati le ṣe awari  to ni ẹ̀bùn atorunwa, ati awọn ti ọwọ wọn dilẹ nípa àìní iṣẹ kan pato ti wọn nṣe, àwọn ọdọ, awọn odobinrin àti Abilekọ ti a wọn ti ka ìwà ipá kọja, awọn ti wọn ti  o n mú oògùn olóró, , awọn onise ọnà, awọn onisegun abalaye, awọn to mọ nípa ewe ati egbo, awọn onimọ nípa oúnjẹ tí o n ṣe ara lóore, awon onkorin/ elere ori itage, awọn oloja, awọn olukọni, awọn ti o n fi owo se owo, awọn ti wọn ohùn alumọni ni ikawọ, awọn onimọ ẹrọ lorisirisi, awọn onimọ sáyẹnsì, awon adari, oludasile, awọn àgbẹ̀, oludasile Ile Ise abele ati ti oke okun, ti wọn yóò darapo lati mú ayipada rere ba okoowo awọn eniyan nile loko ati leyin odi.

12

Fífi ẹsẹ̀ owó múlẹ̀ gìrì

Kan-in-si ajé yóò mú okoowo duro niwon ìgbà ti wón bá ti d’owo pọ pẹlu awọn oludasile, nínú owo idokowo, gbigbe owo kalẹ̀, ifowodokowo pẹlu awọn ise akanṣe Ajo Pan Áfríkà ati ọnà mìíràn lati ko owo jọ.

Eyi ti o jẹ pé a o máa fí kan-in-si ajé san owó tabi ṣe paaṣi-paarọ̀ ni awo ọja lori ẹrọ alatagba ati ọja abẹ́lé wa gbogbo gẹgẹ bi a ti ṣe ilana rẹ kalẹ.

A o se agbekalẹ awọn ida owo kan fún gbígbé àsà  ati idagbasoke àwùjọ . Eyi  yóò mú ayipada  ba áfíríkà títún ti eyi yóò sí jẹ aseyori ti Pan áfíríkà n safẹri fún ti yóò sí mú ala wọn wa sí imu ṣẹ lágbayé.

 

Lakotan

IKan- Owo ajé tayọ kọja owo ori afefe (kiripito)) ni kan, O jẹ igbiyanju lati ro awọn oloja yoruba lágbára pẹlu ìmọ ẹrọ díjítà, eyi yóò sí le jé ki wọn lè ta kongba pẹlú gbogbo awon oloja káàkiri àgbáyé.

IKan-in-si ajé yọ mú ki òjò iwájú rere ba àsà àti eré gọbọi wa fún  okoowo, ti ajinde, ati aabo to pe ba àṣà àjọ Pan Áfríkà ati ẹkọ ti  yóò mú ìṣúná wọn fi ẹsẹ múlẹ nilana ìṣirò I o níí se pèlú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ eniyan èyì ko sí ni àkọsílẹ nínú iṣẹ iwadii wọn lasiko yii.

Iye onka awọn eniyan áfíríkà lasiko yii ni pẹlu Ariyanjiyan jẹ biliọnu kan àbọ̀ (1.5 billion), asiko yi o d dara julọ lati duro ṣinṣin nínú irepo lati isisiyi titi lailai.

É jé kí a jumọ ṣiṣe lati jẹ igbadun Pan Áfríkà bi o ti to ati bini tí yẹ, kí a sowo kí a bẹrẹ òwò owó kan-in-si yíì pẹlu ibamu iṣèdàlẹ́, àṣà ati  ìlànà ìmọ ẹrọ ìgbàlódé.

É dára pọ̀ mọ ajé kan-in-si ti o jẹ ìtọ̀nà ati ìlànà data ti o nṣe àkọsílẹ idokowo ti yóò mú ìdàgbàsókè ba àwùjọ wa loni fún awọn ọmọ Yorùbá , Pan Áfríkà, guusu Amerika ati gbogbo l’ọja lágbayé.

É kan sí wa lori:

Ẹrọ alatagba www.ajecin.io

Email: contactus@ajecoin.io

 

Ask me about AJECOIN